Danny S – Jamisi Lyrics
Danny S – Jamisi Lyrics
Meji loyan, okan loko
what do I know, o ta koko
Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko
Jamisi bo’she nlo, ki lo n d’owo, fi mi si bo she’nlo, ki lo n pa’wo
Jamisi bo’she nlo, oju ti di, fi mi si bo she’nlo, emi gan fe gbowo
Verse
Omo to ba dun, ila ku lala
a brukutu maye ayaku yaya
Lebrete mato mato, anoti oleto le o mato
Oloun gbo
To ba fun e ni pick 2, omo ope gba pick 2
a sun burn ati harmattan, ki la ati harmattan
Won l’oye ki’n pa ara igbeti, eni a bi so’ye, lo’ye n pa
Iku pa mi ti, arun shey mi ti
anybody to ba shey yama yama, eti won bota
Chorus
Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko, Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko
Jamisi bo’she nlo, ki lo n d’owo, fi mi si bo she’nlo, ki lo n pa’wo
Jamisi bo’she nlo, oju ti di, fi mi si bo she’nlo, emi gan fe gbowo
Outro
Iku pa mi ti, arun shey mi ti, anybody to ba shey yama yama
eti won bota
Meji loyan, okan loko
what do I know, o ta koko
All the way from iju, awon omo shaolin temple
all the way from ilu shaku shaku
awon omo ijoba gurumangusu
Awa o kin shey omo jaku jaku